Ìkẹtàlá Ti Megan ni ọ̀wọ́ kejì nínú mẹ́tàlélógún ti Ipele Megan. Ó jẹ́ ọjọ́ ìbí Megan tí ó ní agbára nínú ẹ̀mí. Láti ṣe àjọyọ̀ rẹ̀ pé ó da ọ[dọ́, àwọn òbí rẹ̀ nṣe àpèjẹ nlá kan fún u. Tẹbí tọ̀rẹ́ ni wọ́n pè síbi ayẹyẹ nlá náà, níbi tí olùṣètò orin tí ó jẹ́ akọni rẹ̀, Jack Hammer yóò ti gbé àwọn orin jáde. Ó ndà á rò bóyá ẹnikẹ́ni fi ojú sọ Grrr, àléjò rẹ̀ nlá tíí ṣe ànjọ̀nnú Ẹkùn ará ilẹ̀ Siberia. Kò máa níi ́lọ́kàn láti pàdé àlejò kan tí ó rẹwà lọ́kùnrin. Ipele Ti Megan wà fún àwọn ènìyàn láìfi ti ọjọ́ orí ṣe tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ ti ẹ̀mí.PUBLISHER: TEKTIME

Barnes & Noble is the world’s largest retail bookseller and a leading retailer of content, digital media and educational products. Our Nook Digital business offers a lineup of NOOK® tablets and e-Readers and an expansive collection of digital reading content through the NOOK Store®. Barnes & Noble’s mission is to operate the best omni-channel specialty retail business in America, helping both our customers and booksellers reach their aspirations, while being a credit to the communities we serve.